Orisi iro ohùn meta lo wa ninu ede yourba awin naa ni;

A. Ohùn Ìsàlè (do)
B. Ohùn aarin (re)
C. Ohùn okè (mi
Fi Ami ohùn si awon Oro wonyii
1. Adediwura
2. Adekunle
3. Sugbon
4. Aditu
5. Elemu
6. Ayinla

Ohùn Ìsàlè (do) - Adediwura

Ohùn aarin (re) - Sugbon

Ohùn okè (mi) - Ayinla